Ilé Isẹ́ Ọlọ́pa Nípinlẹ̀ Ọ̀yọ́ Fojú Àwọn Ọ̀daràn Tótó Méjìndínláàdọ́ta Hàn Fáyé

Àwọn tí wọ́n furasí bí ọ̀daràn tótó méjìdínláàdọ́ta tí wọ́ n da ìlú Ìbàdàn àti agbègbè rẹ̀ láàmu ni ilé isẹ́ ọlọ́pa Nípinlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti fojú wọn hàn. Àwọn tí wọ́n furasí bi ọ̀daràn wọ̀nyí lọwọ́ tẹ̀ lórí oníruru ẹ̀sùn bíì ìjìnigbé, ìfipábánilòpọ̀, ìdigunjalè àti […]