Ẹgbẹ Awọn Dọkita to Nkẹkọ Si Lati Di Akọṣẹmọṣẹ Sọpe Awọn Fẹẹ Gunlẹ Iyanṣẹlodi Lọjọbọ

Ẹgbẹ awọn Dọkita to ntewiju lati nimọ si fi di akọṣẹmọṣẹ, lawọn ti ṣetan lati gunlẹ iyanṣẹlodi alainigbedeke lọjọbọ ọsẹ yii, bijọba apapọ baa kuna lati dahun si ibere awọn. Ninu atẹjade eyi ti wọn fisita lẹyin ipade ẹgbẹ naa nilu Abuja, Aarẹ ẹgbẹ naa, […]