Bánki Àpapọ̀ Pàṣẹ Kíwọ́n Gbé Àsùnwọ̀n Àwọn Olùdókowò Orí-Ẹ̀rọ Ayélujára

Àwọn tó ńṣe ìdókowò lórí ẹ̀rọ ayélujára tamọ̀sí Cryptocurrency ni wọ́n ti bẹ̀rẹ̀ si ńṣe ìdókowò wọn lábẹ́nú yàtọ̀ sí èyí táwọn èèyàn mọ̀tẹ́lẹ̀, nítorí àṣẹ bánki àpapọ̀ ilẹ̀ yíì, pé káwọn ilé-ìfowópamọ́ gbé àsùwọ̀n àwọn olùdókowò ohun tì páà. Olùdásílẹ̀ ilé ẹ̀kọ́ kan, tíwọ́n […]