Gómìnà Alágbádá Àkọ́kọ́ Fún Ìpínlẹ̀ Èkó, Lateef Jakande Jáde Láyé

Gómìnà alágbádá Àkọ́kọ́ fún ìpínlẹ̀ Èkó, Àlhájì Lateef Kayọde Jakande ti jáde láyé. Alákoso fọ́rọ̀ isẹ́ òde tẹ́lẹ̀ ọ̀ún ló kú lówurọ̀ òní nílu Èkó léni ọfún mọ́kànléláàdọ́run. Àlhájì Jakande ló jẹ́ Gómìnà ìpínlẹ̀ Èkó láàrin ọjọ́ kini osù kẹwa ọdún 1979 àti ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n […]