O ṣeṣe kile aṣofin keji buwolu iyansipo awọn olori oṣiṣẹ titun Tarẹ Muhammadu Buhari daabaa.

Iroyin so pe, igbimọ tekoto, ti ile yan lati ṣewadi awọn eeyan ọhun yoo jabọ iwadi wọn fun ile aṣofin keji.

Ninu ọrọ rẹ fawọn oniroyin, Alaga Igbimọ Ilẹ F’ọrọ Abo, Ogbẹni Babajimi Bẹnson, sọpe igbimọ naa ti ṣetan lati fabọ rẹ jẹ ile.

Lẹyin ti ile ṣayẹwo awọn ti wọn forukọ wọn sọwọ lọjọru to kọja, ile-igbimo aṣofin agba ṣayẹwo f’awọn eeyan ọhun lotọọtọọ lọjọ ọsẹ to kọja.

Adari ile, Ogbẹni Fẹmi Gbajabiamila, ṣ’agbekalẹ igbimọ kan, eyi ti Ọgbẹni Babajimi Bẹnson lewaju.

Net/Abdulmumin Ishọla

Leave a Reply

Your email address will not be published.